Ẹgbẹ́ Ìsọdàmúsìn Amẹ́ríkà
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti American Colonization Society)
Ẹgbẹ́ Ìsọdàmúsìn Amẹ́ríkà (American Colonization Society ni ekunrere bi, Egbe fun Isodamusin awon Eniyan Adulawo ile Amerika; The Society for the Colonization of Free People of Color of America), to je didasile ni 1816, je egbe fun idapada awon omo African Americans alainidekun si Africa. O sedasile amusin ile Liberia ni 1821–22 gege bi ibi itedo fun awon eni alanidekun. Awon oludasile re ni Henry Clay, John Randolph, ati Richard Bland Lee.[1][2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Bateman, Graham; Victoria Egan, Fiona Gold, and Philip Gardner (2000). Encyclopedia of World Geography. New York: Barnes & Noble Books. pp. 161. ISBN 1566192919.
- ↑ "Background on conflict in Liberia". Archived from the original on 2007-02-14. Retrieved 2011-02-06.