Jump to content

Aminu Tambuwal

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Aminu Waziri Tambuwal, tí a bí ní ọjó kẹ̀wá ọdún 1966. O jẹ́ amòfin àti olóṣèlú. Ó ṣojú ẹkùn gúsù Sókótó gẹ́gẹ bí asofin ni odun 2023. O sin gege bi gomina ipinle sokoto lati ọdun 2015 si 2023. O je ọmọ egbe oselu Peoples Democratic Party. Leyin èyí, o sin gege bi agbenuso kejila fun ile igbinmo asojusofin Nàìjíríà lati odun 2011 si 2015.