Ẹranko
Àwọn ẹranko Animals | |
---|---|
![]() | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Àjákálẹ̀: | |
(unranked) | Opisthokonta |
(unranked) | Holozoa |
(unranked) | Filozoa |
Ìjọba: | Animalia |
Phyla | |
|

Àwọn ẹranko je apa kan ninu awon ohun elemin alahamoarapupo ninu kingdom Eranko.
Kini awon eranko?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awa ni awon eranko yato, dabi awon:

- kiniun, awon ẹkùn, awon alangba, awon ejo, awon maluu, awon adaba, awon owiwi, awon alantakun, awon agbonrin, awon amotèkun, awon ketekete, ati awon eye. Awa ni awon orisirisi eranko ni agbaye wa.
Awon Amotekun: Awon Amotekun saré kiakia, sùgbon, won ko le saré fun akoko ti poju, ti won ba saré, won ma saré fun akoko kekere nigba naa won ma nilo lati ni isnimi.
Awon Kiniun: Awa pe awon kiniun «Oba awon eranko» sugbon o le bere, «kini idi awa n pe won «Oba awon eranko» o ti bere daradara, idi ti awa n pe «Oba awon eranko» je nitori won je «Oba awon eranko» Awon kiniun, won le pariwo pelu ariwo ti o po gan ju gbogbo eranko ni igbo-kijikiji. Ti won ba pariwo, gbogbo eranko won ma saré fun igbesi aye won. Nitori, ko si eranko ni igbo-kijikiji ti o le se jagun pelu kiniun, ti won ba gbiyanju, won ma padanu gidigan. E ma duro pelu awon kiniun.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]{{reflist} eranko igbe