Jump to content

Anuket

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa Òrìṣà Egypt àtijọ́. Fún ìtumọ́ míràn, ẹ wo: Anuket (ìṣojútùú).
Anuket
Script error: The module returned a nil value. It is supposed to return an export table.
The goddess Anuket, depicted as a woman with a tall, plumed headdress
Name in hieroglyphs
a
n
q
t
B1
Major cult centerElephantine, Seheil
SymbolBow, arrows, gazelle, ostrich feather
ParentsKhnum and Satet
Equivalents
Greek equivalentHestia
Roman equivalentVesta

Àdàkọ:Ancient Egyptian religion Anuket jẹ́ Òrìsà àtijọ́ tí ô jẹ́ ọ̀kan láàárín àwọn òrìṣà Orílè èdè Egypt tí apá Ilè Nile àti ní ọwọ́ ìsàlẹ̀ gbogboògbò Nubia, èyí tí ó tún jẹ́ pé àwọn ará Elephantine náà máa ń sìn.[1]

Àwọn ará ilé Egypt tàbí àwọn Elédè Egypt a máa pè ní Anuket, eyi tí wọ́n fàyọ láti Anaka,Àdàkọ:Sfnp tàbí Anqet.[2] Orúkọ tí wọ́n fún yìí ń túnmọ̀ sí Olùgbánǹkanmú tàbí Ẹnití ó ń di nǹkan mú.Àdàkọ:Sfnp Ni ilé Greece, èyí di Anoukis, (Ανουκις),Àdàkọ:Sfnp ìgbà mìíràn en máa ǹ kọ ni Anukis. [3] In the interpretatio graeca, she was considered equivalent to Hestia or Vesta.Àdàkọ:Sfnp

Wọ́n máa ń ṣàpèjúwe Anuket gẹ́gẹ́ bí Obìnrin tí ó ní agbekọ́rí bí tí gélé tabi Irun tí wọn fí Ìyè Ẹyẹ sádárà sí Irun naa. [4] Wọ́n sábà máa ń ṣàpèjúwe rẹ̀ pé ó di Ọ̀pá àṣẹ kan mú tí wọn fí Lankh sórí ọ̀pá náà, Ẹran mímọ́ rẹ̀ sí jẹ́ Àgbọ̀rín.[2] She was also shown suckling the pharaoh through the New Kingdom and became a goddess of lust in later years.[2] In later periods, she was associated with the cowry, especially the shell, which resembled the vagina.[2]

Ìtàn àti àwọn ipa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó jẹ́ ọmọ bíbí Òrìsà Ra, sùgbọ́n ó tán mi Satet ni àwọn àyè ibòmíràn. Fún àpeere, Àwọn Òrìsà méjèèjì yìí ní wọ́n ń pè ní "Ojú Ra" [Eye of Ra], pẹ̀lú àwọn bíi Bastet, Hathor, ati Sekhmet.[2] Also, they were both related in some way to the Uraeus.[2]

Ìsìn tàbí Ìjọsìn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Reliefs of Senusret III and Neferhotep I making offerings to Anuket on Seheil.

Anuket jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òrìṣà meta, Òrìsà Khnum àti Òrìsà Satet tí wọn tún pè ní Satis. Ó sílè jẹ́ pé Anuket ní Àbúrò obìnrin sì Satet tàbí Satis.[4] or she may have been a junior consort to Khnum instead.[4]Àdàkọ:Sfnp

Wọ́n kò Temple ilé ìjósìn kan fún Anuket tí ó wà ní ilé Sehei ní ilé Sehei. Àwọn àkọọ́lẹ̀ kàn fihàn pé ojúbọ́ kan tàbí Pẹpẹ kan ni won yà sí mímọ́ fún-un ní ojúlé yìí láti ọwọ́ Õlọ́fin 13th Farao Sobekhotep III. Lẹ́yìn náà, nígbà Ìṣàkóso kejìdínlógún, Amenhotep II yà ilé ìsìn kan sí mímọ́ fún òrìṣà.[5]

Ní àkókò Ìjọba tuntun, àṣà Anuket ní ilé Elephantine ní kìí wọ́n lo odo fún ìṣẹ̀ṣe oriṣa náà ní oṣù àkọkọ́ tí Shemu. Àwọn àkọọ́lẹ̀ dárúkọ àwọn ìlànà tí wọ́n ń gbà ṣe àjọ̀dún ti Khnum àti Anuket ní àsìkò yìí.[6]

Anouké or Anouki (Anucè, Anucis, Istia, Estia, Vesta), N372.2, Brooklyn Museum

Lọ́pọ̀ ìgbà, nígbà tí odò Náílì bá tí bẹ̀rẹ̀ sí ní kún fún omi ọlọ́ọọdún, àjọyọ̀ Àjọ̀dún Anuket bẹ̀rẹ̀ nìyẹn. Àwọn èèyàn a máa sọ àwọn ohun bíi ẹyọ owó, wúrà tàbí góòlù, àwọn ohun ọ̀ṣọ́ àti àwọn ẹ̀bùn iyebíye sínú odò náà, láti ṣe ìdúpé fún òrìṣà náà fún omi tó ń fúnni ní ìyè àti àwọn àǹfààní tó ń pa dà wá látinú ọrọ̀ àti ìbímọ tí ó ń pèsè. Àwọn ohun èèwò tí ó wàye ní àwọn agbègbè kan ní Ilè Egypt, èyí tí àwọn oúnjẹ bí ẹjá jíjẹ kan ti a kà si mimọ jẹ́ èèwọ̀ fún wọn, padà wá ní ìyọkúrò ní àkokò yìí, èyí tí wọ́n padà gbà ní iyànjú pé irú ẹja bẹ́ẹ̀ tí odò Nile jẹ́ Àmì Anuket ati pé ohun ni kii wọ́n pa wọ́n fún jíjẹ gẹ́gẹ́ bí àwọn ohun ìsẹ̀se fún Àjọ̀dún náà.{Citation needed|date=September 2011}}

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Hart, George (2005), The Routledge Dictionary of Egyptian Gods and Goddesses, Revised Edition, p. 28
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 2.4 2.5 Hill, J. (2010). "Anuket". ancientegyptonline.co.uk. Ancient Egypt Online. Retrieved 2016-10-26. 
  3. Wilkinson, Richard H. (2003). The Complete Gods and Goddesses of Ancient Egypt. New York: Thames & Hudson. pp. 138. ISBN 0-500-05120-8. https://archive.org/details/completegodsgodd00wilk_0/page/138. 
  4. 4.0 4.1 4.2 Geraldine Pinch, Egyptian Mythology: A Guide to the Gods, Goddesses, and Traditions of Ancient Egypt, Oxford University Press, 2004, p 186
  5. Kathryn A. Bard, Encyclopedia of the archaeology of ancient Egypt, Psychology Press, 1999, p 178
  6. Zahi A. Hawass, Lyla Pinch Brock, Egyptology at the Dawn of the Twenty-first Century: Archaeology, American Univ in Cairo Press, 2003, p 443
  • Valbelle, Dominique (1981) (in French). Satis et Anoukis. Verlag Philipp von Zabern. ISBN 3-8053-0414-5. 

Àdàkọ:Ancient Egyptian religion footer

Àdàkọ:Authority control