Jump to content

Aranso

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Aránṣọ ni ẹnikẹ́ní tí ó ti yan láti máa so aṣọ pọ̀ tàbí se àtúnṣe aṣọ tí a ti rán tẹ̀lẹ̀(bíí àpẹẹrẹ, ẹ̀wù, ṣòkòtò àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀lọ) láti mú kí o ṣe déédé ẹni tí a dáa fún un.[1] Aránṣọ gbúdọ̀ jẹ́ ẹni tí ó ti ní ìmọ̀ tẹ́lẹ̀, yálà kí ó ti kọ́ọ ṣáájú tàbí kí ó jogún báa lọ́wọ́ ìyá tàbí bàbá rè. Ẹnikẹ́ni tí ó bá ní ojú ọnà leè sé.

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn gbajúgbajà aránṣọ pọ̀ káàkiri gbogbo orílèèdè lára wọn ni: Yomi casuals, Lumini, Tania, Treasure stitches, Bvic stitches àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀lọ

Àwọn ohun èlò tí a fí n bẹ̀rẹ̀ aṣọ rírán ni:

Òwú

Abẹ́rẹ́

ìwọ̀n

Efun

Áyọ́ọ́nù

sísọ́ọ́sì

Mọsíínì


Àwọn ìtọ́kasí

https://www.google.com/search?q=tailor+definition&oq=tai&aqs=chrome.0.69i59l3j0i20i263i433i512j69i57j46i433i512j69i60l2.5178j1j4&sourceid=chrome&ie=UTF-8

https://www.thesprucecrafts.com/sewing-tools-and-equipment-to-sew-4122025

[2]

  1. "Definition of TAILOR". Merriam-Webster. 2023-02-13. Retrieved 2023-02-14. 
  2. Colgrove, Debbie (2007-02-01). "Build Your Own Sewing Kit With These Essential Tools". The Spruce Crafts. Retrieved 2023-02-14.