Aroko onisorongbesi
Ìrísí
Aroko onisorongbesi
Aroko onisorongbesi ni aroko ti a fi n se itakuoro so laarin eniyan meji tabi juu bee lo.[1]
Abuda Aroko onisorongbesi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- O maa n ni akopa bii ere ori itage
- Oro enu akopa kookan maa n han ni iwaju oruko won
- Iso bee ko gbodo gun ju, ko si se regi
- Oro erin ati awada kii gbeyin, a si gbodo ye ra fun awada ako
- Isesi won ni a maa n fi sinu ani akanmo olofo ()
Awon itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Free online secondary school & High school lesson notes, Classes, etc.". StopLearn. 2023-11-07. Retrieved 2024-01-27.