Jump to content

Asida

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Oúnjẹ Asida

Asida jẹ́ ọ̀kan lára àwọn oúnjẹ tó gbajúmọ̀ láàrin àwọn Lárúbáwá ti ilẹ̀ Áfríkà. Wọ́n maá n pèlòo rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí a ti maá dáná òkèlè. Nígbà mìíràn, wọn a máa sèé pẹ̀lú oyin tàbí bọ́tà.