Jump to content

Assouma Uwizeye

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Assouma Uwizeye
No. 11[1] – APR
Forward
Personal information
Born6 April 1996
NationalityRwandan[2]
Listed height6 ft 0 in (1.83 m)

Assouma Uwizeye (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹrin ọdún 1996) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n ti orílẹ̀-èdè Rwanda, tó sì ń gbá bọ́ọ̀lù náà fún Rwanda Women's National Team.[3]

Iṣẹ́ rè gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ ìdíje àgbáyé

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Uwizeye ṣojú orílẹ̀-èdè Rwanda ní ìdíje 2022 FIBA Africa Women's Champions Cup, níbi tí ó ti gba pọ́íǹtì 9.3 àti àtúnṣe 8.8 lórí ayò kọ̀òkan.[4]

Lásìkò ìdíje 2023 Fiba women’s Zone V AfroBasket Qualifiers, wọ́n ṣe ìdánimọ̀ Uwizeye gẹ́gé bí ọ̀kan lára àwọn tó pegedé nínú gbígbá bọ́ọ̀lù yìí pẹ̀lú, Odile Tetero àti Marie Imanizabayo.[5][6] Bákan náà ni ó kópa nínú ìdíje 2023 Women's Afrobasket níbi tí ó ti jẹ ayò mẹ́fà àti àtúnṣe méjì ní abala àkọ́kọ́ ti ìdíje náà.[7][8]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Assouma Uwizeye, Basketball Player, News, Stats". Eurobasket LLC. 2024-02-10. Retrieved 2024-03-17. 
  2. "Assouma Uwizeye". FIBA.basketball. 1996-04-06. Retrieved 2024-03-17. 
  3. Sikubwabo, Damas (2023-02-19). "Rwanda beaten again as Afrobasket qualifiers leave holes to fill". The New Times. Retrieved 2024-03-17. 
  4. Bahizi, Heritier (2023-08-08). "Rwanda: Meet the Women Who Made Rwanda Proud at 2023 Afrobasket". allAfrica.com. Retrieved 2024-03-17. 
  5. Sports, Pulse (2023-02-19). "Rwanda head coach happy with team’s progress". Pulse Sports Uganda. Retrieved 2024-04-13. 
  6. "TEAM PROFILE: Herculean task for Rwanda as they host 2023 Women’s AfroBasket". FIBA.basketball. Retrieved 2024-04-13. 
  7. Rwabutogo, Atfah Teta (2023-07-30). "Women's Afrobasket2023: Rwandan team – MKU Magazine". MKU Magazine – Empowering Generations Through Education. Retrieved 2024-03-17. 
  8. Abayisenga, Eddy (2023-07-28). "Rwanda Seeks Fourth Place At the FIBA Women’s Afro-basket". KT PRESS. Retrieved 2024-04-13.