Jump to content

Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): G

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

[[Atumo-Ede (Yoruba-English):r]

glue: n; (He stick the broken handle onto the cup with glue.) àtè o fi àte mú owo ìfe tí ó kán náà mó on.

glue: v; (She glued the handle onto the cup.) fi àtè mú ó fi àtè mú owó ìfe náà mo.

gnat: n; (I was bitten by gnats.) kan-in-kan-in kan-in-kan-in je mi gnaw: v; (The rat gnawed a hole in the wooden wall.) ti je; re je; je diedíè.Eku náà re ojú iho je sí ara pako to ìwà lára ìgànà náà.

go: v; (He is going back to his village now.) lo ó n lo padà s;I abúlé rè báyìí.

go: n; (Can I have a go in mending my bicycle.) ìgbìnyanju; ìtèsíwájú N jé mo le ni ìgbìyànjú nípa tílún kèkè mi se

goal: n; (His goal is to go to college.) (He our team got three goals.) opin eré ìje; òpin. Òpin eré ìje ní láti lo sílé-ìwé gíga. Ìrí-àwòn- he; gbígbà bóòlu wonu àwòn. Egbé agbábóòlù wa rí àwòn méta.

goat: n; (Goat is a domestic animal.) ewúré Eran ilé ni ewúré

god: n; (Christians and Muslims believe in one God; in other religions there are different gods for raim, fire, health e.t.c.) olórun Awòn elésìn kìrìsìtééní àti àwon mùsùlùmí gbàgbó nínú olórun an, nínú awon èsùn ìyókù, orísìírísìí àwon olórun ló wà fún; òjò, má, ìlera àti béè béè lo.

gold: n; (She wore a gold ring.) (Her skirt was gold and yellow.) wúrà ó wo òrùka wúrà Awo wúrà Tòbí/yídìípo rè jé aláwò wúrà àti pupa résúrésú.

golden: adj; (The sky was golden in the evening.) aláwò wúrà ojú òrun ní wúrà ní ìrolé.

goldsmith: n; (The goldsmith made ornaments out of gold). alágbède wúrà Alágbède wúrà náà se àwon ohun –òsó tí a fi wúrà se.

good: adj; (Children, be good.) dára; dáradára Èyin omodé: e máa se dáadáa

good: n; (You should take the medicine even if it tastes bad- it is for your own good.) dídara; sànfààní o gbódò lo òògun náà bí ó tìlè koro ó wà fún ànfààni ara re.

goodness: n; (There is a lot of goodness in beans.) ànfààní Ànfààní ló wà lára ewà goods: n; (He sold all his goods before he left the country.) ojà ó ta gbogbo ojà rè kí ó tó fi orílè-èdè sílè.

goose: n; (We keep goose for their eggs and meet.) abo pépéye A máa n sin abo pépeye nitorí àtiyé eyin àti eran jíje.

gorgeous: adj: (The sun was a gorgeous colour yesterday evening.) dídára: híhàn Àwò to dára tí o léwà in òòrùn náà gbé jade ní ìròlé àná.

gorilla: (The hunter killed a gorilla.) ìnàkí ode náà pa ìnàkí kan.

gosling: n; (I bought 3 goslings.) abo omo pépéye mo ra abo omo pépéye meta

gospel: n; (They believe the gospel.) ìhìn rere, ìtàn ìgbe ayé Jèsu; òrò ododo wón gba ìhìn-rere náà gbó.

gossip: n; (I had a gossip with my neighbour and she told me all about the bad behaviour of her sister’s Children.) ofófó; òrò èyìn; àbòsí Èmi pèlí aládùúgbò mi jo se àbòsí lánàá ó sì so gbogbo nnkan fún mí nípa ìwà búburú àwon omo ègbón-ón rẹ̀ obìnrin.

gossip: v; (The old men sat and gossiped all evening.) se àbòsí; sofófó, soro èyìn Awọn bàbá arúgbó náà jókòó wọn si se àbòsí ní gbogbo ìròlé náà.

got: v; (I got a letter from my sister this morning.) rí gbà; rí gbà mo rí létà gba láti òdò egbón ni obìrin ní òwúrò yìí.

gourd: n; (She took the gourd to the well for water.) igbá; kèrègbe; akèngbè ó gbé akèngbe náà lo sí ìdi kanga fún omi.

govern: v; (A lot of people help to govern a country.) sàkóso; sèjoba; solórí òpòlopo ló n sàkóso orílè-èdè kan.

government: n; (Our government has decided to build more school and hospitals this year.) ìjoba; alákòóso Ìjoba wa ti pinnu láti kó àwon ilé-iwé àti àwon ilé ìtóju àwon aláìsàn síi odún yìí.

governor: n; (My father is a governor.) gomínà; olórí; bale Gomínà ní bàbáà mi.

gown: n; (She has many gowns.) èwù ìlekè gígùn ó ní òpòlopò èwù ìlekè gígùn.

grab: v; (He grabbed the book from his friend and ran away.) já nnkan gbà ó já ìwé náà lówó ore rè ó sí sálo.

grace: n; (Let us stand up and say the grace.) oore-òfé E jé kí a dìde dúró kí a se oore òfé

graceful:adj; (The men did a graceful dance.) dídára; léwà Àwon okunrin náà jó ijó tí ó dára.

gracious: adj; (He gave her a gracious smile.) olóore-òfé; aláànú ó fi èrín pàdée rè tàánú tàánú.

grade: n; (We have three grades of eggs.) (Grade A eggs are the largest and Grade C the smallest.) ipò/ìpín bí nnkan se rí orísìí ìpín méta ni àwon eyin náà bí won se tóbi sí. Àwon tó wà ni ipò kínní (Grade A) lo tóbi jù nígbà ti awon to wà ni ìpín keta (Grade C) ló kèré jù.

grade: v; (They have graded the eggs into several sizes.) pín sí ìpín/ipò bí nnkan se rí Wón ti pín àwon eyin náà sì bí wón ti se tóbi sí.

gradual: adj; (There has been a gradual improvement in your work.) díèdíè Àyípadà díè ti bá isée rè.

gradually: adv; (Babies learn to walk gradually.) díedíè; ní sísè-n-lèlé Àwon omo owo n ko bí a ti se n rin díedíè.

graduate: n; (She is a history graduate from an American college. akékòógboyè Akékòógboyè nínú ìmò ìtan lati ilé èkó giga ti ilè Améríkà kan.

graduate: v; (She graduated in history.) kékòó gboyè ó kekòó gboyè nínú ìmò ìtan.

grain: n; (Grain is used for making flour.) (A few grains of salt lay on the table.) okà A máa n fi okà se ìyèfun. Nnkan tín-ún Iyò tín-ún wà lórí tábìlì. grammar: n; (English grammar is quite difficult to learn.) ìmò ìlo òrò/èdè dajudájú Ìmò ìla edè oyìnbó nira láti kó díe.

gramophone: n; (The gramophone is not loud enough.) ero agbòhùngbohùn Ero agbohùngbohùn náà kò lo sókè to.

grand: adj; (The government buildings were very grand.) tóbi, lóla; wuyì; níyìn; léwà Àwon ilé ìjoba náà tóbí wón sì Léwà.

grandchild: n; (My grandchild is here.) omo-omo omo-omo mi wà níbì.

granddaughter: n; (She is my granddaughter.) omo-omo to jé obìnrín. omobinran omo mi ni.

grandfather: n; (My grandfather was a hunter.) babáa bàbá ode ni bàbáa bàbá mi.

grandmother: n; (My grandmother was a trader.) ìyáàyà (ìyá ìyá) onísòwò ni ìyáàyá mi.

grandson: (My grandson is living with me.) omokùnrin omo mi omokùnrin omo mi n gbe pèlú mi.

granite: n; (He built his house with granite.) irúfé òkúta kan to máa n le ó fi òkúta lílè kó ilé rè.

grant: v; (The Children were granted a holiday because the examination results were so good.) gbà; fi fún ; fí jínkí Wón fi ìsimi jínkí àwon akékòó náà torí pe àwon èsì ìdánwò wón dára gidi.

grant: n; (The government gave us a grant to build another Classrom.) ohun tí a fúnni; èbùn fún isé Ìjoba fún wa ni èbùn owó láti fi kó yàrá ìkàwé mìíràn.

grape: n; (We are in the season of grapes.) èso àjàrà. A ti wà ní àkókò èso àjàra.

grapefruit: n; (The grapefruit is not sweet.) osàn apàárà. Osàn àpáàrà náà kò dun.

graph: n; (They made a graph of how hot the weather was in that month.) ìlà àjúwe. Won se ìlà ajúwe fún bí ojú ojó ti se gbóná to nínú osù náà.

graph-paper: n; (He bought a graph-paper.) irúré ìwé kan tí ó máa n ní ihò fótótótó tí a n lò fún ìlà ajuwe ó rá ìwa tí a n lò fún ìlà ajuwe.

grasp: v; (I grasp the cat by the back of its neck and put it outside.) (I couldn’t grasp what the English teacher told me.) gbá mú; dí mú mo gba olóngbò náà léyìn orùn mú, mo sì tìí síta. yé; mòye N kò lè mòye nnkan. Tí olùko èdè Gèésì náa so fún me

grass: n; (We sat on the grasses to eat our food.) koríko. A jókòó lórí koríko láti je oúnjẹ wa.

grassland: n; (Grassland is very good for cattle rearing.) ilè oníkoríko Ile oníkoríko dára fún itóju maalu

grasshopper: n; (Grasshoppers are very common during the dry season.) eléngà; taata. Taata máa n wópò nígbà èèrùn.

grate: v; (She grated the cassava tubers.) rin; lò ha. Ó rin egé naa.

grate: n; (The grate is no more good.) irin ìkélé-irin tí o wà ní ìsàlè ìdáná níbi níbi tí eérú n bá jade. Irin ìkélé náà kò dára mó.

grateful:adj; (I am very grateful to you for giving me these books.) moore; lópè mo dupe lowo re fún pé o fún mi ni àwon ìwé yìí.

gratitude: n; (I an full of gratitude to yo for the books ìmoore: ìdúpé mo fi ìmoore han sí o fún àwon ìwé náà.

grave: n; (She visits her father’s grave every week.) ìbójì; saárè ó máa n lo be ibojì bàbáa rè wò lósòòsè.

gravel: n; (There was a gravel path from the gate to the front door.) okúra wéwèèwé ojú ona tí o ní òkúta wéwèèwé wà láti enu ibodè náà títí dé ilèkun abáwolé.

graze: n; (It that a cut on your knee?- No, it is only a graze.) ara bíbó N jé ojú ogbé ni ti ojú eékún re yen-Rárá, ojú ara bíbó lásán ni.

graze: v; (Cattle were grazing in the field.) (He grazed his kneel when he fell down.) je koríko. Awọn máàlù n je koríko lórí papa. Fi ara bo nípa fifi lo nnkan Ó fi orokun/eékan re bo nigba ti ó subu.

grease: n; (If you put grease lin your car wheels, they turn more easily.) òrá; epo; ìpara Tí o ba fi epo sí àwon àgbá esè okò re won yòó máa yí pèlú ìròrùn si.

grease: v; (You must keep this machine greased.) fi epo sí; fi òrá sí ; fi ìpara pa ó gbódò máa fi epo sí èro yìí díéde.

great: adj; (We learnt about great people in history.) tóbi; pípò nlá A kó nípa àwon ènìyàn nlà nínú ìtàn.

greed: n; (He is not hungry, but he can’t stop eating those chocolates-it is just greed.) ìwora; ojúkòkòrò Ebi kò paá sùgbón kò le se kó má je àwon mìndin-mín-ìn-din yen-ìwora lásán ni!

greedy: adj; (My brother is greedy.) ní ìwora Egbon mi ni ìwora.

green: n; (The painter used different sorts of green for the plants in his picture.) àwò ewé olùkun-nnkan náà lo orisìírisìí tí ó je mó àwò ewe fun àwon ohun ògbìn nínú àwòran tí ó yà.

green: adj; (She wore a gren dress.) tí o ní àwò ewé ó wo aso aláwò ewé.

greet: v; (He greeted me.) (The new idea was greeted with surprise.) ki; yò mó ó kí mi. Jo-kí èrò jo. Èrò tuntun náa jo pèlú ìyanu.

grew: v; (Your orange tree grew up very fast.) so; dàgbà Igi osàn re yára dàgbà.

gray: adj; (There was a grey cat on the wall.) tí kò dúdú tí ko funfun olóngbò kò dúdú-kò-funfun kan wa lána ogiri.

gray: n; (I don’t like gray.) àwò tí ko dúdú tí ko funfun N ko féràn àwo tí kò dúdú ti kò funfun.

grief: n; (She was made weak with grief when her son died.) ìbànújé Nígbà lí omo rè kú, ìbànújé mú kí ó rè e.

grin: n; (I have been given some money! he said with a grin.) èrín ìyànyí; èrín ègàn Won ti fún mi lówó díè! Ó sòrò pèlú èrín ako.

grin: v; (Why are you two boys sitting grinning at each other instead of doing your work?) rérìn-ín ako; rérìn-ín ègàn bóyín kí ló dé tí èyin omo kùnrin méjèèjì yìí fi jókòó tí e n rérìn-ín ako sí ara yín dípò tí è ba’fi máa sise yín?

grind: v; (We grind grain to make flour.) lòA máa n lo okà láti fi se ìyèfun.

grind-stone: n; (He grinded the pepper on a grind-stone.) olo; okúta ìho nnkan ó lo ata náà lórí olo.

grip: v; (The Child was gripping hen mother’s hand.) dì mú sinsin; gbá mú omo náà di owó ìyáa rè mú.

grip: n; (He grip was so strong that her mother couldn’t take her hand away.) ìdìmú; ìgbámú ó di; di iyáa re mú dé ibi pé ìyá re kò lè já owó kúrò.

groan: v; (He groaned with pain.) ké ìrora; gbin ó gbin pèlú ìrora.

groan: n; (He gave a groan of pain.) ikérora o ní ikérora.

groove: n; (When we play a record, the needle moves along very small groves. ìtèbò Nígba tí a bá n gbó awo orin abéré tí o máa n mú àwo korin síta máa n bá àwon ihò ìtèbò tín-ín-rín tin-in-rún ojú àwo tí ó n korin náa yí.

ground: n; (His book fell to the ground.) ilè Iwé rè bó sílè. groundnut: n; (I ate groundnuts.) èpà mo je èpà.

group: n; (A group of girls was waiting outside the school.) akójopò; egbé Akójopò àwon omodé bìnrin dúró sí ìwájú ìta ilé ìwé náà

group: v; (They were grouped round their teacher.) kóra jo pò wón kóra jo pò yí olùkó won po.

grove: n; (The had a grove mango-trees behind their house.) oko igi tí o jé iru igi kan náà ló wà níbè Wón ni oko igi mángóòrò léyìn ilé won.

grow: v; (The Children grow up fast.) (The weather grew colder.) dàgbà Àwon omo náà n yára dàgbà dì; dà ojú ojó ti di tútù.

growth: n; (The Child’s growth was fast.) ìdàgbàsoke Ìdàgbàsókè omo náà yá díadáa.

growl: v; (The dog growled at the visitors.) kùn Ajá máa kùn mo àwon àlejò náa.

grub: n; (There were a lot of grubs under the stone.) kòkòrò kékeré tí kò tìí gún ìyé. Àwon nkòkòrò tí ko tìí gún ìyé pò lábé okúta náà. Ounjẹ́ Oúnjẹ ti se tan Grub is up.

grumble: v; (She is always grumbling about the Children making a noise.) kùn o máa n kun sáa nítorí àwon omo tó n pariwo.

grumpy: v; (The little girl was grumpy because she was tuned and hung any.) ìgbónára omodébinrin náà ni ìgbónára nitorí pé ó rè e, ebí sì n pa á.

grunt: v; (Pigs were grunting in the yand.) kùn bí elédè Àwon elédè n kùn nínú ogbà.

grunt: n; (The pigs gave a loud grunt.) kíkùn elédè; ariwo elédè kíkùn àwon elédè náà lo soke.

guarantee: n; (I give him my guarantee to work for you for a year.) èrí Mo fún un lérìí pé kí ó bá o sisé fún odún ken.

guarantee: v; (Can you guarantee to work for me for a year, or will you be leaving soo?) se ilérí N jé o le se ilérí pé wà a sisé fún mi fún odún kan tabí o fé padà bayìí? guard: v; (The dog guarded the house.) só; dáàbò bò. Ajá náà dáàbò il;e náà.

guard: n; (As I walked into the army camp, the guards stopped me.) (The solders were on guard all night. aláàbò; otùsó Bí mo se rìn dé ìtèdó àwon omo ogun náà, àwon olùsó náà dá mi dúró. Ìsó; ààbò : ìdáàbòbò Àwon ológun náà lóri ìsó ní gbogbo oru.

guardian: n; (I live with my guardians in the town.) alágbàtó ; olùtójú mo n gbe pèlú àwon alágbàtó mi nínú ilú náà.

guirdance: n; (My teacher gave me guidance in English language.) ìtósónà; ìfònàhàn olùkó mi fún mi ní ìtósónà nínú ede Gèésí.

guave: n; (I ate guares yesterday. gírófà – irúfè eso kan tí won máà n je ní tutu mo je gírófà lánàá.

guess: v; (“How old is the Child” “I guess he is ten”) rò so “omo odún mélòó ni omo náà? “mo ro ó pé odún méwàá ní.

guest: n; (We try to make our guests happy.) àlejò; alápèje. A gbìyànju láti mú kí inú awon àlejò wa dùn.

guide: v; (He was guided by what I said.) fi ònà han; tó sí ònà òrò tí mo so ló tó o sí ònà.

guide: n; (He is a guide and shows visitors around the town.) amònà ó jé amònà, o sì n fi àjíká ìlí náà han àwon alejò.

guilt: n; (I felt guilt when I spent all his money.) ebi ese: ese mo rí pé mo ní èbi èsè nígbà tí mo ná gbogbo owó re.

guilty: adj; (The criminal was proved to be guilty.) tí ó dá èsè; ní èbi èsè Wón débí èsè ru òdaran náà.

guinea-corn: n; (He has grinded his gunea-coms.) okàa bàbá ó ti lo okà bàbà rè.

guinea: (He has killed his guinea fowl.) fowl; n; eye awó ó ti pa eye àwoo rè.

guinea: pig: n; (He breeds guinea pigs.) eku emó; emó òyìnbó o n tóju àwon emó.

guinea-worm: n; (The Child has guinea-worm.) sòbìà omo náà ní sobìa.

guiter: n; (He bought a new guiter.) wáyà- irúfé ohun èlò orin kan tí a máa n ta ó ra wáyà tuntun.

gully: n; (The rain ran through the gullies.) ojú àgbàrá; òjo náà n sáré gba àwon ojú agbara náà.

gulp: v; (He gulped down the bear and ran out of the house.) sáré gbé mì ó saré gbé otí náà mì ó sì sare jade nínú ilé.

gum: n; (There is gum on the back of a stamp.) (He has cut his gum with a spoon) (He fell the gum tree (eucalyptus)) àtè, oje igi Àtè wà léyìn ìwé kékere tí a máa n lè mó léta. Ìsàlè eyín Ó ti fí sibí ge lbi ìsàlè eyún rè. Igi àtè Ó gé igi àtè náà lule.

gum: n; (The soldiers all carried their gums.) ìbon Gbogbo àwon omo ogun náà gbe ìbon won.

gum:-powder: n; (The bullets are made to move by gum-powder burning.) ètu ìbon Jíjò ètu ìbon ló máa n mú ota jade nínú ìbon.

gurgle:v; (The little river gurgled over the Stores.) tu pùùpùù: hó omi odò kékeré náà n tu pùùpùù koja lórí awon òkúta náà.

gust: n; (A stranger gust tore a branch off the tree.) aféfé òjiji tí ó le Aféfé ojiji ti ó le púpò náà ya èka igi náà kúrò.

gut: n; (He removed the gut of the gout.) ìfun eran ó ko ìfun ewúré náà kúró.

guts: n; orí ekó o ni èkó tó láti le síwajú nínú isé tó lágbára náà.

gutter: n; (I had to clear the gutter because it was blocked with dead leaves.) ìgbàsòòrò; òsòòròmo ní láti gbá ojú ìgbàsòòrò náà nítorí pè àwon ewé ti díi.

gymnastics: n; (We do gymnastics in a gymnasium.) idárayá A máa n se idáraya in ìbi ìsìdárayá.