Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): O

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Atumo-Ede (Yoruba-English): Ọ

ọtí bàbà, n. guinea-core beer.

ọtí ìrèké sweet wine, sugar-cane beer.

ọtí kíkan, n. sour liquor, vinegar.

otí òjò, otí titun, n. unfermented liquor.

ọtí ẹ̀dá, n. old fermented wine.

ọtí olójèé, ọtí jìínì, n. trade gin.

ọtí yangan, n. corn beer.

ọtọ̀, n, adj. different, alone, separate

ọtọ̀ ni bàtà yìí yàto (This shoe is different.)

ọ̀tọ̀kú ìlú, n. the town elders, noblemen or wise men.

ọ̀tọ̀tọ̀, n. the whole of anything, entirety, many. ọ̀tọ̀tọ̀ ènìyàn ni ó wá sí orí pápá. (Many people came to the field.)

ọ̀tun, n. or adj. newness, freshness, novelty, new, fresh, recent, novel. ọ̀tun nìwé yìí. This book is new.

ọ̀túnla, adv. day after tomorrow. Wa sí ibí ní ọ̀túnla. (Come here on the day ofter tomorrow.)

ọ̀wá, n. branch of the palm tree, east wind, stagger.

ọwààrà, n. shower of rain, anything thrown or scattered.

ọ̀wàwà, n. an animal resembling the dog, which climbs the tree with its face, downwards, and its hind legs topmost, tree-bear.


ọ̀wẹ̀, n. a club or a company summoned to assist one of their number in manual labour. Mo bẹ wọ́n ní ọ̀wẹ̀ lórí iṣẹ́ oko mi. I asked them for assistance with my farm-work.

ọ̀wèǹgà, n. name generally applied to sierra Leonean immigrants, probably suggested the plenty fulness of ‘wanga’- a species of fish common in sierra Leone.

ọ̀wẹ̀rẹ̀, n. a kind of fish resembling mackerel.

ọ̀wọ̀, n. honour, respect (He shows honour to his parents.) ó fi ọ̀wọ̀ fún àwọn òbí rẹ̀.

ọwọ́, n. hand, branch, spray

ọwọ̀, n. broom, besom.

ọ̀wọ́ ẹran, n. herd of cattle, drove.

ọwọ́ ìjà (erin), n. trunk (of the elephant)

ọwọ́ iná n. flame of fire, blaze.

ọwọ́lẹ̀, n. time opportunity. Ó tún mi ní ọwọ́lẹ̀ láti ṣe e. (He gave me the opportunity to do it.)

ọ̀wọ́n, adj. dearth, scarcity, dearness, dear. Ọ̀rẹ́ mi ọ̀wọ́n. (My dear friend.)

ọ̀wọ́n adj. dear, scarce.

ọ̀wọ̀n, n. pillar.

ọ̀wọ̀n àwọ̀ọsánmọ̀, n. pillar of cloud.

ọ̀wọ̀n ilé, n. house-pillar.


ọ̀wọ́nlówọ̀n-ọ́n, adv. dearly. ọ̀wọ́nlọ́wọ̀n-ọ́n ni wọ́n ra ìṣẹ́gun. (victory was bought dearly.)

ọ̀wọ̀n ògiri, n. pillar of wall.

ọwọ́ òsì, the left hand.

ọ̀wọ́ ọkọ̀, n. fleet, collection of ships, navy.

ọwọ́ ọ̀tún, n. the right hand.

ọ̀wọ̀wọ̀, n. dry corn boiled soft for food.

ọ̀wun, n. vengeance, retaliation, recompense, blame; a weaver.

ọ̀yà, n. wages, salary, hire, pay, stipend, an animal which is also called ‘Ewújù,’ hedgehog, bush pig. (His wages are ten naira per week.) owó ọ̀yà rẹ̀ jẹ́ náírà mẹ́wàá lọ́sẹ̀.

ọya, n. wife of ṣàngó, to whom the River Niger is dedicated, hence the river is called ‘Odò Ọya’ after her.

ọyá, n. string or cord made of grass, chisel.

ọyá, ẹyá, n. Knife used for incising palm-trees for obtaining palm-wine.

ọ̀yájú, n. saucy fellow, cheeky or presumptuous. (You cheeky monkey.) Ìwọ òyájú ọ̀bọ yìí.

ọyàn, n. the same as ‘Omú’ which see breast of a woman.

ọ̀yàyà, n merry mood and behavious, cheerfulness, vivacity. ọ̀yàyà rẹ̀ ni ó jẹ́ kí ó ní ìfẹ́ sí i. (He was charmed by his vivacity.)

ọ̀yẹ̀, n. twilight, beginning of the dawn. ọ̀yè ń làá bọ̀. (It is almost dawn.)

ọyẹ́, n. the harmattan, the cool wind that blows in West Africa during December.

ọyinyin, n. one spoiled by indulgence, a spoilt child.

oóyẹ́, ewéédú, n. a viscous vegetable used for soup.

ọ̀yọ́mìsì, ọ̀gọ́mèsì, n. a title of respect conferred on the leading elders of ọ̀yó

ọyún, ètútú, èétú, n. matter coming out of a sore, purulence, pus. Má ṣe fún oówo láti fi agbára jẹ́ kí ọyún rẹ jáde. Dọ́nt squeeze a boil to force the pus out.