Jump to content

Atlantic slave trade

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Pp-protect

Stowage of a British slave ship, Brookes (1788)
Reproduction of a handbill advertising a slave auction in Charleston, British Province of South Carolina, in 1769.

Àdàkọ:Slavery Ìsòwò Ẹrú níAtlantic tàbí transatlantic slave trade jẹ́ tàbí ìgbà tí àwọn oníṣòwò Ẹrú bá gbé àwọn èèyàn aláwọ̀ dúdú Kúrò gẹ́gẹ́ bí eru láti orílé Áfíríkà lọsí Amẹ́ríkà. Àwọn ará Yúróòpù wọn á máa lo ọkọ̀ ojú omi ẹrú tí wọ́n fi ń ṣe òwò ẹrú máa ń lo ọ̀nà ìṣòwò onígun mẹ́ta àti Arin Àárín inú Atlantic déédéé, ó sì wà láti ọ̀rúndún kẹrìndínlógún sí Ṣẹ́ńtúrì kọkàndíńlógún[1]Púpọ́ júlọ nínú àwọn tí wọ́n gbé lọ fún ìṣòwò ẹrù nipasẹ̀ transatlantic jẹ́ àwọn ènìyàn láti àárín Africa àti Ìwọ̀-oòrùn Africa tí Àwọn onísòwò ẹrú tí Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà tí tà sí àwọn oníṣòwò ẹrú bíi àwọn Portuguese, British, Spanish, Dutch, ati Faranse tí àwọn náà ń tá ẹrù.[2][3][4] nígbà tí àwọn míìràn tí wọn mú tààrà nípasẹ àwọn oníṣòwò ẹrú ní àwọn ibi ogun létí òkun

;[5] Àwọn oníṣòwò ẹrú ní ilẹ̀ Yúróòpù kóra jọ, wọ́n sì fi àwọn tí wọ́n wà lẹ́rú sẹ́wọ̀n láwọn ibi olódi ní etíkun Áfíríkà, wọ́n sì kó wọn wá sí ilẹ̀ Amẹ́ríkà.[6][7]Àyàfi Àwọn arà ìlu Portugal, àwọn oníṣòwò ẹrú Yúrópù ní gbogbogbò kò kópa nínú àwọn ikọlù nítori ìrètí ayé fún àwọn ará ìlù Yúrópù tí wọ́n wà ní ni ihà ìsàlẹ̀ aṣálẹ Sahara, èyí wáyé láárin ọdún kan láàárin àkókò tí ìṣòwò ẹrù (èyítí ó jẹ́ ìṣààjúu ní gbá tí ààrùn ibà wà ní jákèjádò tí wọn sí fí quinine ṣe ìtọjú iba náà.[3]Àwọn Orílẹ̀-èdè tí wọ́n wà ní apá Gúsù Atlantic ati ìletò Carribbean gbáralẹ́ àwọn Ẹrú fún ẹ̀tọ̀ ọrọ-aje wọ́n àti àwọn iṣé oríṣiríṣi èyí tí iṣé Ìrèké àti àwọn ohùn ọ̀gbìn mìíràn náà wà níbẹ̀. Èyí ní àwọn ará ilè Ìwo oòrùn Yórùpù wó pé ó jẹ́ òhun pàtàkì ti won sì ń bá àwọn orílé èdè miiran ní òpin 17th àti 18th Sẹ́ńtúrì, tí wọ́n ń bá ará wọn jà latiy sẹ̀dá Ìjọba tí ó ga júlo lórí àwọn ilù òkèrè (Colonial Empire).[8]

Ìpìlẹ Abẹ́lẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Ẹ wo

  1. "The history of the transatlantic slave trade". National Museums Liverpool. 10 July 2020. Retrieved 26 March 2021. 
  2. Henry Louis Gates Jr. (April 22, 2010). "Opinion – How to End the Slavery Blame-Game". The New York Times. https://www.nytimes.com/2010/04/23/opinion/23gates.html. Retrieved March 22, 2022. "The historians John Thornton and Linda Heywood of Boston University estimate that 90 percent of those shipped to the New World were enslaved by Africans and then sold to European traders." 
  3. 3.0 3.1 Sowell, Thomas (2005). "The Real History of Slavery". Black Rednecks and White Liberals. New York: Encounter Books. p. 121-122. ISBN 978-1-59403-086-4. 
  4. Thornton, p. 112.
  5. "The transatlantic slave trade". BBC. Retrieved 2021-05-06. * Some of those enslaved were captured directly by the European slave traders. Enslavers ambushed and captured local people in Africa. * Most slave ships used European 'factors', men who lived full-time in Africa and bought enslaved people from local leaders. 
  6. "Implications of the slave trade for African societies". London: BBC. Retrieved 12 June 2020. 
  7. "West Africa – National Museums Liverpool". Liverpool: International Slavery Museum. Retrieved 14 October 2015. 
  8. Mannix, Daniel (1962). Black Cargoes. The Viking Press. pp. Introduction–1–5. https://archive.org/details/blackcargoeshist00mann.