Atsede Bayisa
Ìrísí
Atsede (centre) leading at the 2012 Chicago Marathon | |
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Kẹrin 1987 Dire Dawa, Ethiopia |
Sport | |
Orílẹ̀-èdè | Ethiopia |
Erẹ́ìdárayá | Women's Sport of athletics |
Achievements and titles | |
Personal best(s) | Marathon: 2:22:03 (2012) Half marathon: 1:07:34 (2013) |
Atsede Bayisa Tesema ni a bini ọjọ kẹrin dinlogun, óṣu April ni ọdun 1987 jẹ elere sisa lóbinrin ti ilẹ Ethiopia to da lori ayẹyẹ sisa ere loju ọna[1][2]. Bayisa yege ninu Marathon ti Chicago, Marathon ti Boston ati Marathon ti Paris lẹẹmeji.
Àṣèyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Atsede ṣoju fun órilẹ ede Ethiopia nibi to ti kopa ninu ere sisa IAAF agbaye ti óju ọna ni ọdun 2007[3][4]. Atsede gba ami ẹyẹ ti ọla silver ninu ere gbogbo ilẹ afirica ni ọdun 2007. Ni ọdun 2009, Arabinrin naa kopa ninu idije agbaye lori ere sisa[5].