Awon ara Ṣainiisi ni ile Naijiria
Ìrísí
Awọn ara Ṣáínà ni ile Naijiria
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awọn ara ilu Ṣáínà ti n gbe ni Naijiria pọ gidigan, lara sì jẹ awon Ṣáíniisi ti wọn bí sí Naijiria pelu irandiran Hakka.
Itan iṣiwa sí ilẹ Nàìjíríà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni Ọdún 1930, a ka awọn Ṣainiisi pẹlu iran Hakka mẹrin ti n gbe ni ile Nàìjíríà. Awọn oniṣowo ti ilu hongi kongi bẹrẹ si n ṣi ile iṣẹ sílẹ ní ọdún 1950. Nígbàtí o di ọdún 1965, awọn bíi ìgbà omo ṣáínà ni won wa ni Naijiria. Ni ọdún 1999, iye awon ṣáíniisi ti n gbe ni Nàìjíríà ti di Ẹgbàata din ni igba (5,800) pẹlu ojì-din-lẹwá le ni ẹgbẹ́ta (630) omo tewan ati ọta-din-lẹwá din ni ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́fà (1050) omo ilu Họngi kọngi.