Jump to content

Ayẹyẹ ọdún ìbílẹ̀ Fao

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ayẹyẹ ọdún ìbílẹ̀ Fao jẹ́ èyí tí àwọn olóyè àti ènìyàn Navrongo ní apá Ìlà-oòrùn ilè Ghana.[1] Wọ́n máa ń ṣàjọyọ̀ yìí ní oṣù Ṣẹẹrẹ lọ́dọdọdún.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 "Festivals in Ghana". www.ghanaweb.com. Retrieved 27 December 2011.