Ayobo, Lagos
Ìrísí
Ayobo je igberiko kan ni ijoba ibile Alimosho ni ipinle Eko, guusu-iwoorun Naijiria . [1] ibè ni Ile-ẹkọ giga Anchor, Lagos [2]
Ayobo ni ilu ti o kẹhin ni ilu Eko ni àlà Aiyetiro, ipinle Ogun. Ayobo jẹ ilu ti o ni awọn agbegbe mewa labẹ rẹ. Megida, Isefun, Olorunisola, Bada, Sabo, Kande-Ijon, Orisumbare-Ijon, Jagundeyi, Alaja, àti bebe lo.
Megida ati Isefun ni awon ilu ti o gbajugbaja jùlo labe Ayobo. Megida sì ni olu ilu Ayobo, ìbi ti a kale Yunifasiti Anchor sí. Isefun/Kande-Ijon sì jẹ ibi ti a ún ko okan lára Lagos Water Ways.
Ayobo pin Agbegbe Idagbasoke ìjoba ìbílè pèlú Ipaja (Agbegbe idagbasoke ipaja/Ayobo).
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Video: "Ghettorization" Of The Poor People Of Lagos: Ayobo-Ipaja Road 12 Years Waiting!". Sahara Reporters. 15 December 2010. http://saharareporters.com/2010/12/15/video-ghettorization-poor-people-lagos-ayobo-ipaja-road-12-years-waiting. Retrieved 4 February 2016.
- ↑ "PASTOR KUMUYI builds N1 billion Anchor University permanent campus". Ecomium Magazine. 30 October 2013. Archived from the original on 13 May 2016. https://web.archive.org/web/20160513121750/http://encomium.ng/pastor-kumuyi-builds-n1-billion-anchor-university-permanent-campus/. Retrieved 4 February 2016.