Jump to content

Bayo Omoboriowo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Báyọ̀ Ọmọ́boríowó)
Báyọ̀ Ọmọ́boríowó
Ọjọ́ìbí13 Oṣù Kàrún 1987 (1987-05-13) (ọmọ ọdún 37)
Orílẹ̀-èdèNigeria
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Lagos
Iṣẹ́Official photographer to President Muhammad Buhari
Olólùfẹ́Lola Omitokun[1][2]
Websitebayoomoboriowo.com

Bayo Omoboriowo (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàlá oṣù karùn-ún ọdún 1978) jẹ́ ayawòrán-kọròyìn ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni ayàwòrán àgbà fún Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́wọ́́lọ́wọ́, Muhammadu Buhari.

Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọmọ bíbí ìlú Èkó ni Báyọ̀ Ọmọ́boríowó. Kódà, Muṣin, ní ìlú Èkó lo tí dàgbà.[3] Báyọ̀ kàwé gboyè dìgírì nínú ìmọ̀ Applied Chemistry ní ifáfitì tí ìjọba àpapọ̀ tí ó wà ní ìpínlẹ̀ Èkó, University of Lagos.[4][5]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]