Jump to content

Bọlaji Ẹniọla Maryam

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ẹ̀niọla Maryam jẹ àkọṣemọṣẹ elere badminton orilẹ ede Naigiria ti à bini 21, óṣu september ni ọdun 2005 ni ilu ibadan ṣugbọn ó dàgbà si ipinlẹ kwara Naigiria. Arabinrin na fi oju si ere tennis tẹlẹ tẹlẹ ki oto wa dipe o pada si ère badminton[1].

Bọlaji jẹ ẹni akọkọ ni ilẹ Afirica lati gba gold ni championship lori badminton ti o si pegede lati lọ kopa ni ere idije badminton ni ilu japan[2][3].

  1. https://badmintonafrica.com/bolaji-mariam-eniola-road-to-para-badminton-glory/
  2. https://www.thecable.ng/eniola-bolaji-makes-history-as-first-african-to-win-para-badminton-championship/amp
  3. https://newsdiaryonline.com/abdulrazaq-elated-as-bolaji-wins-gold-medal-in-world-badminton-championship/