Jump to content

Baba ghanoush

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Baba ghanoush, oúnjẹ àwọn Lárúbáwá

Baba ghanoush jẹ́ oúnjẹ amébipanú kan tí wọ́n maá n pèlò ní ilẹ̀ Lárúbáwá. Wọn a máa pẹ̀lo rẹ̀ pẹ̀lú èso ìgbá tí wọ́n ti gún àti àwọn orísirísi èrònjà mìíràn. Wọn a máa jẹ Baba ghanoush pẹ̀lú àlùbọ́sà tàbí nígbà mìíràn pẹ̀lú ata tòmátò.