Babátúndé Ọlátúnjí

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Babatunde Olatunji)
Jump to navigation Jump to search
Babátúndé Michael Ọlátúnjí
Percussion master Babatunde Olatunji on the cover of his groundbreaking 1959 release Drums of Passion
Percussion master Babatunde Olatunji on the cover of his groundbreaking 1959 release Drums of Passion
Background information
Ọjọ́ìbí(1927-04-07)Oṣù Kẹrin 7, 1927
Ajido, Lagos State, Nigeria
Ìbẹ̀rẹ̀New York City, United States
AláìsíApril 6, 2003(2003-04-06) (ọmọ ọdún 75)
Irú orinWorld music
Occupation(s)Musician
InstrumentsDrums
Years active1959–2003
LabelsColumbia, CBS, Narada, Virgin, EMI
Websiteolatunjimusic.com
Babatunde Olatunji, second from right, at the Tal Vadya Utsav International Drums & Percussion Festival, Siri Fort Auditorium, New Delhi, 1985

Babátúndé Michael Ọlátúnjí tí wọ́n bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹrin ọdún 1927, tí ó sìn kú ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹrin ọdún 2003 (April 7, 1927 – April 6, 2003) jẹ́ gbajúmọ̀ àyàn, olùkọ́ni, ajàfẹ́tọ̀ọ́ àwùjọ àti onímọ̀ agbohùnsílẹ̀ ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ṣùgbọ́n tí ó tẹ̀dó sí Amẹ́ríkà. [1]Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "The Nigerian drummer who set the beat for US civil rights". BBC News. 2020-09-01. Retrieved 2020-09-05.