Ọ̀gẹ̀dẹ̀
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Banana)
Ọ̀gẹ̀dẹ̀ Banana | |
---|---|
Peeled, whole, and cross section | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Ìjọba: | |
(unranked): | |
(unranked): | |
(unranked): | |
Ìtò: | |
Ìdílé: | |
Ìbátan: |
Ọ̀gẹ̀dẹ̀ jẹ́ èso gígùn tó ṣe é jẹ,[1][2] èyí tí àwọn igi eléso mìíràn ní genus Musa máa ń jẹ jáde.[3] Ní àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn, wọ́n máa ń dín ọ̀gẹ̀dẹ̀, wọ́n sì máa ń yà wọ́n sọ́tọ̀ sí èyí tó wà fún jíjẹ. Èso náà máa ń wà ní oríṣiríṣi ìwọ̀n, àwọ̀ àti ìrísí, àmọ́, ó máa ń gùn tó sì máa ń rí ṣọnṣọ, pẹ̀lú ara tó rọ̀.
Àpèjúwe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Igi ọ̀gẹ̀dẹ̀ jẹ́ igi eléwé tó tóbi jù lọ.[4] Ìsàlẹ̀ igi ọ̀gẹ̀dẹ̀ jẹ́ èyí tí wọ́n máa ń pè ní "corm".[5] Igi náà máa ń ga, tó sì máa ń dúró nílẹ̀ dáadáa. Kò sí orí ilẹ̀ tí ọ̀gẹ̀dẹ̀ ò ti lè hù, ní bí i 60 centimetres (2.0 ft) sínú ilẹ̀, ó sì fẹ̀ dáadáa.[6] Igi ọ̀gẹ̀dẹ̀ jẹ́ èyí tó máa ń tètè hù nínú gbogbo àwọn igi eléso yòókù. Ìwọ̀n ìdàgbàsókè ojoojúmọ́ rẹ̀ jẹ́1.4 square metres (15 sq ft) to 1.6 square metres (17 sq ft).[7][8]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedmorton
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedArmstrong
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedMW
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedPicqINIB00
- ↑ Stover & Simmonds 1987, pp. 5–9.
- ↑ Stover & Simmonds 1987, p. 212.
- ↑ Verrill, A. Hyatt (1939). Wonder Plants and Plant Wonders. New York: Appleton-Century Company. p. 49 (photo with caption).
- ↑ Flindt, Rainer (2006). Amazing Numbers in Biology. Berlin: Springer Verla. p. 149.