Bazin
Ìrísí
Bazin jẹ́ irúfẹ̀ búrẹ́dì tí àwọn ará orílè-èdè Líbíyà maá n jẹ. Wọ́n maá n pèlo rẹ̀ pẹ̀lú ríro èlùbọ́ bálì lórí iná, wọ́n sì maá n jẹẹ́ pẹ̀lú obẹ̀ tòmátò, ẹyin, òdùkú, àti ẹran àgùntàn.