Jump to content

Beauty and the Dogs

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán fíìmù Beauty and the Dogs

Beauty and the Dogs jẹ fiimu ere-idaraya 2017 ti Kaouther Ben Hania ṣe agbejade re. O ṣe afihan ni abala Cannes Film Festival ti odun 2017.[1][2] Wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí i ìgbàwọlé fun Best Foreign Language Film ni ilu Tunisia ni ayeye okanlelaaadorun-un 91st Academy Awards,[3] sugbon ko wole fun igba ami eye na.[4]

Ọdọmọbinrin ara ilu Tunisia kan ni awọn ọlọpaa fipa ba ni ajosepo ati pe o wa iranlọwọ ni awọn ile-iwosan ati awọn agọ ọlọpa lati forukọ irufin wọn sile lakoko ti o si wa labẹ ipaya ikọlu naa. O pade aibikita, ikorira, awọn idiwọ ijọba ati iranlọwọ die lati ọdọ awọn eniyan oriṣiriṣi ti o paade. Ni ipele ti o kẹhin, ọpọlọpọ awọn ọlọpa n wa lati dẹruba odomobirin yii di igba ti ọkan ninu awọn oṣiṣẹ naa yapa kuro ninu ẹgbẹ awon to korira odomobirin naa, osi gba niyanju laati tesiwaju pelu edun re. Da lori itan otitọ.

  • Mariam Al Ferjani bi Mariam Chaouch
  • Ghanem Zrelly bi Youssef Youssef
  • Noomen Hamda bi Chedly
  • Mohamed Akkari bi Lamjed Lamjed
  • Chedly Arfaoui bi Mounir
  • Anissa Daoud bi Faiza
  • Mourad Gharsalli bi Lassaad
  1. "The 2017 Official Selection". Cannes Film Festival. Retrieved 13 April 2017. 
  2. Winfrey, Graham (13 April 2017). "2017 Cannes Film Festival Announces Lineup: Todd Haynes, Sofia Coppola, 'Twin Peaks' and More". IndieWire. Penske Business Media. Retrieved 13 April 2017. 
  3. Neila, Driss (16 September 2018). "Oscars 2019 – Le film "La belle et la meute" de Kaouther Ben Hania représentera la Tunisie à la présélection". Tunis Webdo. Retrieved 16 September 2018. 
  4. Kozlov, Vladimir (19 September 2018). "Oscars: Tunisia Selects 'Beauty and the Dogs' for Foreign-Language Category". The Hollywood Reporter. Retrieved 19 September 2018.