Benjamin Akande

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Benjamin Ola Akande
Akande in 2022
Senior Vice President, Director Human Resources, Head of Diversity and Inclusion
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
Oṣù Kàrún 1, 2021 (2021-05-01)
Stifel Financial
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1962
Nigeria
(Àwọn) olólùfẹ́Bola Taiwo Akande
Àwọn ọmọ3
ResidenceSt. Louis, Missouri
Alma materWayland Baptist University
University of Oklahoma
ProfessionBusiness Leader
Economist
Academic

Benjamin Ola Akande jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America, tó sì tún jẹ́ onímọ̀, ọ̀jọ̀gbọ́n àti oníṣòwò ńlá. Ní oṣù May, ọdún 2021, wọ́n fi sípò ìgbá-kejì ààrẹ, Director Human Resources, Head of Diversity and Inclusion, Stifel Financial, èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìfowópamọ́ tó ń rí sí ìdókòwò. Òun ni ààrẹ kọkànlélógún ti Westminster College ní Fulton, Missouri.[1][2][3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "National Headliners". Jet (Jet (Johnson Publishing Company)) 102 (10): 10. Aug 26, 2002. ISSN 0021-5996. https://books.google.com/books?id=nLUDAAAAMBAJ&pg=PA10. 
  2. "Yoruba in America demand better performance, accountability from Buhari". The Guardian (Nigeria). July 8, 2015. http://guardian.ng/news/yoruba-in-america-demand-better-performance-accountability-from-buhari/. Retrieved July 8, 2015. 
  3. Rebecca Rivas (May 8, 2015). "Webster University's Benjamin Akande named president of Westminster College". The St. Louis American. http://www.stlamerican.com/news/local_news/article_42436114-f5a1-11e4-888e-e70f31a22bcc.html. Retrieved July 8, 2015.