Jump to content

Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé-Plateau

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Benue-Plateau State)
Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé-Plateau

Ipinle Benue-Plateau je ipinle tele ni Naijiria. O je dida ni 27 May 1967 lati awon apa Agbegbe Apaariwa o si wa titi di 3 February 1976, nigba ti won pin si ipinle meji - Benue ati Plateau. Ilu Jos lo je oluilu re nigbana.


Awon Gomina Ipinle Benue-Plateau

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]