Betty Abah

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Betty Abah
Betty Abah at Wiki event (cropped).jpg
Abah in 2015
Ọjọ́ìbíOṣù Kẹta 6, 1974 (1974-03-06) (ọmọ ọdún 46)
Otukpo, Benue State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́
  • oníróyìn
  • akọ̀wé
  • ajíjágbara fún àwọn ọmọdé àti àwọn obìnrin

Betty Abah (bíi ni ọjọ́ kẹfà oṣù kẹta ọdún 1974) jẹ́ oníróyìn, akọ̀wé àti ajíjágbara fún àwọn ọmọdé àti àwọn obìnrin. Òun ni olùdásílẹ̀ àti adarí fún CEE HOPE ní ìlú Èkó.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bíi Betty sì ìlú Otukpo ni ìpínlè Benue. Ó gboyè nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ èdè gẹ̀ẹ́sì láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Calabar, ó sì tẹ síwájú nínú ẹ̀kọ́ náà ni University of Lagos.

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ pẹlu ilé iṣẹ́ tí ó ń ṣe ìwé ìròyìn tí The Voice Newspaper ni ìpínlè Benue. Ó ti si ṣé pelu àwọn ìwé ìròyìn bíi Newswatch, Tell Magazine àti Rocky Mountain news.[1] Ó ti kọ àwọn ìwé bíi Sound of Broken Chains, Go Tell Our King àti Mother of Multitude.[2][3] Ó dá ẹgbẹ́ CEE-HOPE kalẹ̀ ni oṣù kejìlá ọdún 2013.[4][5][6]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]