Billie Lourd

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Billie Lourd
Lourd ní ọdún 2015
Ọjọ́ìbíBillie Catherine Lourd
Oṣù Keje 17, 1992 (1992-07-17) (ọmọ ọdún 31)
Los Angeles, California, U.S.
Ẹ̀kọ́Harvard-Westlake School
Iléẹ̀kọ́ gígaNew York University (B.A.)
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́2015–present
Olólùfẹ́
Austen Rydell (m. 2022)
Àwọn ọmọ2
Parents
Àwọn olùbátan

Billie Catherine Lourd[1] (tí a bí ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gún oṣù keje ọdún 1992)[2] jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orilẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi l Chanel #3 nínú eré Fox tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Scream Queens (2015–2016) àti ipa rẹ̀ nínú FX tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ American Horror Story (2017–títí di ìsinsìnyí). Ó farahàn gẹ́gẹ́ bi Lieutenant Connix nínú àwọn eré Star Wars sequel (2015–2019). Lourd nìkan ni ọmọ òṣèrébìnrin Carrie Fisher.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Fisher, Carrie (2008). Wishful Drinking. Simon and Schuster. p. 121. ISBN 978-1-4391-5371-0. https://books.google.com/books?id=2f1nyv9Pi80C&pg=PA121. 
  2. Martin, Annie (July 17, 2017). "Billie Lourd celebrates 25th birthday at rainbow-themed bash". United Press International. Retrieved July 15, 2018.