Billy Crudup

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Billy Crudup
Crudup ní ọdún 2015
Ọjọ́ìbíWilliam Gaither Crudup
Oṣù Keje 8, 1968 (1968-07-08) (ọmọ ọdún 55)
Manhasset, New York, U.S.
Ẹ̀kọ́University of North Carolina, Chapel Hill (BA)
New York University (MFA)
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́1989–present
Olólùfẹ́
Naomi Watts (m. 2023)
Alábàálòpọ̀Mary-Louise Parker
(1996–2004)
Claire Danes
(2004–2006)
Àwọn ọmọ1

William Gaither Crudup ( /ˈkrdəp/; tí a bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù keje ọdún 1968)[1] jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orilẹ-èdè Amẹ́ríkà. Ipá rẹ̀ nínú fíìmù Jesus' Son (1999) jẹ́ kí wón yàn mọ́ àwọn tí ó tó sí Independent Spirit Award for Best Male Lead. Ó tún ṣeré nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré bi Almost Famous (2000), Big Fish (2003), Mission: Impossible III (2006), Watchmen (2009), Public Enemies (2009), The Stanford Prison Experiment (2015), Jackie (2016), àti Alien: Covenant (2017).

Crudup gba àmì-ẹ̀yẹ Tony Award fún ipa rẹ̀ nínú fíìmù Tom Stoppard tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ The Coast of Utopia (2007). Ó tún ti ṣeré nínú àwọn eré bi Gypsy (2017), The Morning Show (2019), èyí tí ó mú kí ó gba àmì-ẹ̀yẹ Primetime Emmy Award àti Critics' Choice Television Award.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Birthdays". The Modesto Bee. Associated Press: p. 2A. July 8, 2022. "Actor Billy Crudup is 54."