Bobotie
Ìrísí
Bobotie jẹ́ oúnjẹ tó ṣẹ̀ wá, tó sì tún wọ́pọ̀ ní orílẹ̀-èdè Gúúsù Áfríkà. Wọn a máa pèlo rẹ̀ pẹ̀lú lílọ ẹran kúnná, èyí tí wọn ó sè pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn èrònjà títí yóó fi jinná dé ààrin kan. Lẹ́yìn náà, wọn ó parí rẹ̀ pẹ̀lú dída ẹyin àti mílìkì si lórí.