Bolot Feray
Ìrísí
Bolot Feray | |
---|---|
Adarí | Jean-Claude Matombe |
Olùgbékalẹ̀ | Marie-Therese Choppy |
Òǹkọ̀wé | Marie-Therese Choppy |
Àwọn òṣèré | Alain Belle Charles DeCommarmond Jenita Furneau Antonia Gabriel Marie Lista |
Orin | Conrad Damou Patrick Morel |
Ìyàwòrán sinimá | Vincent Joseph Humbert Mellie |
Olùpín | SBC |
Déètì àgbéjáde | 1995 (Seychelles) |
Àkókò | Ìṣẹ́jú Márùndínlàádóje |
Orílẹ̀-èdè | Seychelles |
Èdè | French |
Bolot Feray, jẹ eré oníṣe aláwàdà Seychellois ti ọdún 1995 tí Jean-Claude Matombe jẹ́ olùdarí Marie-Therese Choppy sì ṣe àgbéjáde rẹ̀. ògbóǹtarìgì òsèré Alain Belle ni ipa titular tí Charles DeCommarmond, Jenita Furneau, Antonia Gabriel ati Marie Lista kó ipa àtìlẹyìn. O da lori ere kan ati ṣafihan aṣa àti ìṣẹ̀dálẹ̀ awujọ Seychellois.
Eré oníṣe náà gba àtúnyẹ̀wò rere àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì ẹ̀yẹ níbi ayẹyẹ eré oníṣe àgbáyé. Eré oníṣe náà jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn eré Áfíríkà tí ó dára jùlọ. Geva René ẹni tí ó kọ eré náà ní àkọ́kọ́.
Òṣèré
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Alain Belle bi Bolot Feray
- Charles DeCommarmond bi Arakunrin Sarl
- Jenita Furneau bi Mari
- Antonia Gabriel bi Pierreline
- Marie Lista bi Poupet
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]