Brik

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Oúnjẹ Brik

Brik jẹ́ oúnjẹ tó gbajúmọ̀ ní apá árèwá Áfríkà, pàápàá jùlọ ní orílẹ̀-èdè Tùnísíà. Ó jẹ́ ẹ̀yà oúnjẹ tí wọ́n maá n ṣe látara èròjà bíi èlùbọ́ ẹ̀gẹ́, ẹyin, ẹja, ata àti àwọn èròjà mìíràn.