Briouat
Ìrísí
Briouat jẹ́ oúnjẹ tó gbajúmọ̀ ní apá árèwá Áfríkà, pàápàá jùlọ ní orílẹ̀-èdè Mòrókò. Ó jẹ́ ẹ̀yà oúnjẹ tí wọ́n maá n ṣe látara èròjà bíi èlùbọ́ ẹ̀gẹ́, mílìkì, ẹran, ata àti àwọn èròjà mìíràn. Lọ́pọ̀lọpọ̀ ìgbà, oríṣi ẹran méjì tí wọ́n maá n sábàálò ni ẹran ẹdìyẹ tàbí ẹran àgùntàn.