Buari

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Buari se ilu kan ni Ipinle Kwara ni guusuiwoorun Naijiria, awon omo Yoruba ngbe. Ilu naa pin aala pẹlu Okeya, Egi, Ilala ati Esie.