Jump to content

Bubu Mazibuko

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Bubu Mazibuko je òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà.[1] [2]Ó kọ ipa Betsy nínú eré Catch a Fire ni ọdún 2006.[3] Ó kọ ipa Thuli nínú eré Gaz'lam (2002-2005)[4], èyí sì lọ jẹ́ kí wọn yàán fún òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ Duku Duku Awards.[5] Fún ipá Lindiwe tí ó kó nínú eré Man on Ground (2011) ni wọn ṣe yàán fún òṣèré tí ó dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ Africa Magic Viewer's Choice Award.[6][7]

Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Catch a Fire (2006)
  • Gangster's Paradise: Jerusalema (2008)
  • A Small Town Called Descent (2010)
  • Man on Ground (2011)
  • Mandela: Long Walk to Freedom (2013)