Prince Buster
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Cecil Bustamente Campbell)
Prince Buster | |
---|---|
Prince Buster performing in 2008 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Cecil Bustamente Campbell |
Ọjọ́ìbí | Kingston, Jamaica | 24 Oṣù Kàrún 1938
Ìbẹ̀rẹ̀ | Jamaica |
Aláìsí | 8 September 2016 Miami, Florida, U.S. | (ọmọ ọdún 78)
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Years active | 1961–2016 |
Labels |
|
Cecil Bustamente Campbell Àdàkọ:Postnominals (24 May 1938 – 8 September 2016), tó gbajúmọ̀ bíi Prince Buster, jẹ́ akọrin, akọ̀wé-orin àti olóòtú ará Jamáíkà. Àwọn orin rẹ̀ ní ìgbà àwọn ọdún 1960 ló ṣe ìpilẹ̀sẹ̀ orin ayéòdeòní ilẹ̀ Jamáíkà.[1]