Chacha Eke
Ìrísí
Chacha Eke Faani | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Charity Chinonso Eke 17 July 1987 Ìpínlẹ̀ Ebonyi, Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Ọmọ Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Ebonyi State University |
Iṣẹ́ | Òṣèrébìnrin |
Ìgbà iṣẹ́ | 2009– àkókò yìí |
Gbajúmọ̀ fún | eré ṣíṣe |
Notable work | Olùdásílẹ̀ Print-Afrique Fashion Ltd |
Olólùfẹ́ | Austin Ikechukwu Faani (m. 2013) |
Charity Chinonso Eke, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Chacha Eke Faani, tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrìndínlógún oṣù keje ọdún 1987 jẹ́ Òṣèrébìnrin ọmọ Ìpínlẹ̀ Ebonyi lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó di gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́ká nígbà tó Kópa nínú sinimá kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ The End is Near lọ́dún 2012 .[1]
Ìgbésí ayé rẹ̀ ní èwe, ìkẹ́kọ̀ọ́ àti iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó bẹ̀rẹ̀ ilé-ìwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ ní ESUT Nursery & Primary School ní Ìpínlẹ̀ Ebonyi , lẹ́yìn máa ó kàwé ní Our Lord Shepherd International School ní Enugu.[2] Ó kàwé gboyè BSc ní Ebonyi State University nínú ìmọ̀ Ìṣirò-owó.[3]
Àtòjọ àwọn àṣàyàn sinimá àgbéléwò rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- The End is Near
- Commander in Chief
- Clap of Thunder
- Two Hearts
- Beach 24
- Gift of Pain
- A Cry for Justice
- Jewels of the Sun
- Bloody Carnival
- Cleopatra
- Dance For The Prince
- Mirror of Life
- Innocent Pain
- Bridge of Contract
- Palace of Sorrow
- Secret Assassins
- Royal Assassins
- The Promise
- Valley of Tears
- Village Love
- Weeping Angel
- Rosa my Village Love
- My Rising Sun
- My Sweet Love
- Secret Palace Mission
- Stubborn Beans
- Bitter Heart
- Shame to Bad People
- Beauty of the gods
- Pure Heart
- Rope of Blood
- Hand of Destiny
- Lucy
- Sound of Ikoro
- Omalicha
- Bread of Sorrow
- Basket of Sorrow
- Festival of Sorrow
- Kamsi the Freedom Fighter
- Pot of Riches
- Girls at War
- Crossing the Battle Line
- Money Works With Blood
- Happy Never After
- Who Took My Husband
- Roasted Alive
- Song of Love
- My Only Inheritance
- Royal First lady
- Beyond Beauty
- After the Altar
- Bloody Campus
- Princess's Revenge
Bondage
- ’’My Last Blood’’
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "NOLLYWOOD ACTRESS CHACHA EKE AND HUSBAND SHARED ADORABLE PHOTOS TO MARK 2ND YEAR ANNIVERSARY". Naijezie. 1 June 2015. Archived from the original on 11 July 2017. Retrieved 23 October 2015.
- ↑ "Charity ‘Chacha’ Eke". Naij. Retrieved 23 October 2015.
- ↑ Agadibe, Christian (26 July 2015). "Motherhood transformed me –ChaCha Eke". The Sun News. Archived from the original on 29 August 2015. https://web.archive.org/web/20150829112045/http://sunnewsonline.com/new/motherhood-transformed-me-chacha-eke-2. Retrieved 23 October 2015.