Jump to content

Chama cha Kiswahili cha Taifa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Chama cha Kiswahili cha Taifa (National Kiswahili Association, CHAKITA) jẹ́ àjọ Kenya kan tí wọ́n dá kalẹ̀ ní ọdún 1998 láti gbé Èdè Swahili lárugẹ ní Kenya.[1] Alága àkọ́kọ́ àjọ náà ni Ọ̀jọ̀gbọ́n Kimani Njogu, akẹ́kọ̀ọ́ gboyè láti ẹ̀ka Linguistics ti Yunifásitì Yale.[2]

Àwọn isẹ CHAKITA ni láti ṣe ìwádìí èdè Kiswahili language àti láti sise pẹ̀lú àwọ̀n ilé ẹ̀kọ́ láti gbé èdè Kiswahili lárugẹ àti láti lòó fún ìdàgbàsókè orílẹ̀ èdè. Ní ọdún 2000, ilé ìgbìmò asofin Kenya ṣisẹ́ lórí ìgbìmọ̀ CHAKITA láti sọ Kiswahili di èdè orílẹ̀ èdè, tí wọ́n sì pọn kíkó rẹ̀ ní àwọn ilé ìwé ní dandan.[1] Wọ́n fún Clara Momanyi, akọ̀wé CHAKITA ní íṣẹ ògbùfọ̀ Ìwé òfin Kenya sí èdè Kishwahili, a sì fọwọ́ sí ògbùfọ̀ náà ní 2010 referendum.[2]

CHAKITA tún ti ran ìjọba lọ́wọ́ láti gbé àwọn èdè Kenya míràn lárugẹ.[1] CHAKITA tún ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn àjọ míràn tí ó ń gbé èdè Kishwahili lárugẹ, àwọn bi as BAKITATanzania àti Uganda.[1][3]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 Njogu, Kimani. "Language policy in Kenya: the opportunities, the challenges". In Mugane, John M.. Linguistic typology and representation of African languages. Africa World Press. pp. 69–82. ISBN 1-59221-155-0. 
  2. 2.0 2.1 Mazrui, Alamin M. (2016). Cultural Politics of Translation: East Africa in a Global Context. Routledge. pp. 118–126. ISBN 9781317233190. https://books.google.com/books?id=iliaCwAAQBAJ&q=CHAKITA. 
  3. Schadeberg, Thilo C. (2009). "Loanwords in Swahili". In Haspelmath, Martin; Tadmor, Uri. Loanwords in the World's Languages: A Comparative Handbook. De Gruyter Mouton. p. 76.