Cheikh ndiaye
Ìrísí
Cheikh Ndiaye je òṣèré àti ònkọ̀wé láti ìpínlè Senegal. [1]. Ó ka editing and filmmaking ní Free Conservatory of French Cinema (CLCF) ní ìpínlè Fránsì.Ó ṣe àgbéjáde ìwé ìtàn mẹ́rin pẹ̀lú SIRA Badral ati àwọn fíìmù ìtàn-àkọ́ọ́lé méjì.[2]