Chelsea F.C.

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ikọ̀ Bọọlu aláfẹsẹ̀gbá Chelsea jẹ ile-iṣẹ bọọlu alamọde Gẹẹsi kan ti a da ni ọdun 1905. Wọn n dije ni Premier League, ipin kìńní ti bọọlu Gẹẹsi. Chelsea wa laarin awọn ẹgbẹ tí ó ṣe àṣeyọrí jùlọ ni ìlú England. Wọn ti bori ọgbọn idije tí Premier League, pẹlu awọn akọle oke-oke mẹfa, ife FA mẹ̀jọ, ife UEFA Europa méjì, ife UEFA Cup Winners méjì, ife UEFA Champions League ẹyọ kan, ati UEFA Super Cup ẹyọ kan. Ile ilẹ wọn ni Stamford Bridge ni Fulham, ni ìlú London.

Stamford Bridge tí ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Chelsea ńlò