Child harvesting in nigeria

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Child harvesting in nigeria o tumo si pe ona ti awon eniyan gba bi omo ni ona ti ko bojumu, ati bi awon alagbato ni awon ilu nla se n gba omo to fun idi kan tabi omiran.eyi tumo si fifi omo se pasiparo lori eto igbokegbodo oro aje ni tipatipa ati agidi.Opolopo awon omodebinrin ti ojo ori won koju omo odun mejidinlogun si ogun odun lo,o ijoniloju lo je lati ri wipe awon domodebinrin ti won se awon nkan wonyi ko rii bi nkan ti ko bojumu lawujo wa. [1]

Oja[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

FIfi awon omode se okoowo je oun to dabi owo eru laarin awujo wa,Awon onisowo eru ni lati wa si aarin oja nibi ti won se karakata awon

odomode binrin ati okunrin wonyi .Nigbana ni olukaluku yio maa se dunadura awon eniyan wonyi,Ni opolopo igba ni awon olowo eru yii maa nlo awon eniyan wonyi fun ise ti koboju mu.Gege bi omo oodo ati ise asewo.[2]

Awon itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Reporters, Sahara; York, New (2015-12-03). "Horrors Of Nigerian Child Harvesting Revealed In New Documentary". Sahara Reporters. Retrieved 2022-03-30. 
  2. Geoghegan, Andrew (2009-09-15). "Fly Away Children". ABC Online. http://www.abc.net.au/foreign/content/2009/s2686908.htm. Retrieved 27 November 2010.