The Notorious B.I.G.
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Christopher Wallace)
The Notorious B.I.G. | |
---|---|
Fáìlì:The Notorious B.I.G.jpg Wallace in 1995 | |
Ọjọ́ìbí | Christopher George Latore Wallace Oṣù Kàrún 21, 1972 Brooklyn, New York, U.S. |
Aláìsí | March 9, 1997 Los Angeles, California, U.S. | (ọmọ ọdún 24)
Cause of death | Shooting |
Orúkọ míràn |
|
Iṣẹ́ | Rapper |
Ìgbà iṣẹ́ | 1992 | –1997
Olólùfẹ́ | Faith Evans (1994–1997; his death) |
Àwọn ọmọ | 2 (T'yanna and Christopher Jr.) |
Musical career | |
Irú orin | |
Labels | |
Associated acts | |
Christopher George Latore Wallace tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkànlélógún oṣù karùn-ún ọdún 1972, tí ó sìn kú lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù Kẹta ọdún 1997 (May 21, 1972 – March 9, 1997) jẹ́ olórin tàkasúfèé ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ bí Biggie Smalls lẹ́yìn tí ó kópa nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ (Let's Do It Again) lọ́dún 1975, àti Big Poppa, pẹ̀lú The Black Frank White, bẹ́ẹ̀ náà nínú sinimá àgbéléwò (King of New York),[1] sugbon gangan pelu oruko ori itage re The Notorious B.I.G..
Wallace dagba ni adugbo Brooklyn ni Ilu New York.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Notorious B.I.G.: In His Own Words, And Those of His Friends Archived 2007-03-11 at the Wayback Machine. (March 7, 2007). MTV News. Accessed 2007-03-11.