Climate change in Algeria

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ìyípadà ojú-ọjọ́ ní Algeria ni ipa tí ó gbòòrò lórí orílè èdè tí náà. Algeria kìí ṣe olùkópa pàtàkì sí ìyípadà ojú ọjó, ṣùgbọ́n bíi àwọn orílẹ̀ èdè tó kù lára àgbègbè MENA, ó yẹ kí o wá lára àwọn tí ó ní ipa nípa àyípadà ojú-ọjọ́. Nítorí ibi ńlá kan tí orílẹ̀ èdè náà wà ní ìgbèríko tí ó gbóná, pẹ̀lú apá tí Sahara tí ó gbóná. Ní ọdún 2014,àwọn onímọ̀ ẹ̀rọ ń kópa nínú wíwá àdíkù bá àyípadà ojú-ọjọ́ ní orílè èdè Algeria. Algeria wá ní ipò 46 tí àwọn orílẹ̀ èdè ní ìṣe àyípadà ojú-ọjọ́ tí ọdún 2020.