Jump to content

Kọ́ndọ̀mù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Condom)
Kọ́ndọ̀mù
Kọ́ndọ̀mù kikaKọ́ndọ̀mù
Kọ́ndọ̀mù kikaKọ́ndọ̀mù
Kọ́ndọ̀mù kika
Ìpínsọ́wọ̀ àti àwọn òkunfà ìta


Kọ́ndọ̀mù (condom) jẹ́ ohun èlò ìdènà tí o ní irisi àpòfẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ tí a n lò lakoko ìbálòpò láti dínkù ìṣeeṣe oyún tàbí (STI).[1] Kọ́ndọ̀mù ti akọ àti abo ló wà.[2] Pẹ̀lú lílo dáradára àti lílo ni gbogbo ìgbà ìbálòpò - àwọn obìnrin tí àwọn alabàṣepọ̀ wọn n lo kọ́ndọ̀mù ọkùnrin ní rírí Òṣùwòn oyún 2% fún ọdún kan.[1] Pẹ̀lú, oṣuwọn oyun jẹ 18% fun ọdun kan.[3] Lilo wọn dinku eewu gonorrhea, chlamydia, trichomoniasis, jedojedo B, ati HIV/AIDS.[1] Wọ́n tún máa ń dáàbò bò ó lọ́wọ́ àwọn egbòogi ìbílẹ̀, papillomavirus ènìyàn (HPV), àti syphilis.[1]

A ti yi kọ́ndọ̀mù ọkùnrin naa sori kòfẹ ti o duro ṣinṣin ṣaaju àjosepọ̀ àti ṣiṣé nípa dídida ìdènà ti ara eyiti o ṣe idiwọ àtọ lati wọ inu ara ti alábàṣepọ̀ ìbálòpò.[4] [5] Àwọn kọ́ndọ̀mù akọ jẹ́ deede láti inú latex àti tí o kéré jùlo, láti polyurethane, polyisoprene, tàbí ìfun ọ̀dọ́-àgùntàn.[4] Àwọn kọ́ndọ̀mù ọkùnrin ní àwọn ànfàní ti ìrọ̀rùn ti lílò, irọrun àrọ́wótó, àti àwon ipa ègbẹ díè (àbàwón).[4] Nínu àwọn ti o ní áléjì latex kan yẹ kí o lo polyurethane tàbí ẹèyà sintetiki miran.[4] Àwọn kọ́ndọ̀mù obìnrin jẹ deede láti polyurethane àti pé o le ṣee lò ní ọ̀pọ̀lọpò ìgbà.[5]

Lati ọdun 1954 ni àwon kọ́ndọ̀mù ti sise gẹ́gẹ́bí olùdènà àrun STI.[6] Àwọn kọ́ndọ̀mù rọ́bà ti wà láti ọdún 855, leyin naa ni àwọn kọ́ndọ̀mù tuntun mi wáyé lọdun 1920.[7] [8] kọ́ndọ̀mù wà nínu àwon ohun èlò ti o se pataki julo ti (Akojọ Awọn oogun Pataki) ti Ajo Agbaye fun Ilera yan.[9] Iye owo osunwon ni agbaye to sese ndagbasoke jẹ nipa 0.03 si US$0.08 kọọkan. Ní Orílè Amẹrika, owó tí wón n ta kọ́ndọ̀mù je US$1.00.[10] Ní káríayé díè bi ìdámèwá (less than 10%) gbogbo àgbáyé ni àwọn tí won ñ lo kọ́ndọ̀mù fun ìfètò sómo bíbí je.[11] Òṣùwòn lílo kọ́ndọ̀mù ga julọ ni àwon ìlú àgbáyé ti won ti ni ìrírí ìdàgbàsókè. Ní odun 2018, bi 5.1% ni lilo kọ́ndọ̀mù jé l'orile Naijiria nigbati ni ìwo oòrùn Afirika (Western Africa) Jé 3.9%.[12] Ni United Kingdom kọ́ndọ̀mù jẹ ohun èlò ònà kejì tó wópò jùlọ fún ìfètò somo bibi (22%) nigbati ni orile Amerika, o je ohun èlò keta to wópò julo fún ifeto somo bibi (iṣakoso ibimọ) (15%).[13] [14] O fẹrẹ to bilionu mẹéfa si mẹsan ni a ta ni ọdun kan.[15]

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 Hatcher, Robert Anthony; M.D, Anita L. Nelson (2007) (in en). Contraceptive Technology. Ardent Media. pp. 297–311. ISBN 9781597080019. Archived from the original on 2017-09-18. https://web.archive.org/web/20170918185600/https://books.google.com/books?id=txh0LpjjhkoC&pg=PA297. 
  2. WHO Model Formulary 2008. World Health Organization. ISBN 9789241547659. 
  3. Trussell, J. "Contraceptive efficacy". Ardent Media. Archived from the original on 2013-11-12. https://web.archive.org/web/20131112130150/http://www.contraceptivetechnology.org/wp-content/uploads/2013/09/CTFailureTable.pdf. 
  4. 4.0 4.1 4.2 4.3 Hatcher, Robert Anthony; M.D, Anita L. Nelson (2007) (in en). Contraceptive Technology. Ardent Media. pp. 297–311. ISBN 9781597080019. Archived from the original on 2017-09-18. https://web.archive.org/web/20170918185600/https://books.google.com/books?id=txh0LpjjhkoC&pg=PA297. 
  5. 5.0 5.1 Speroff, Leon; Darney, Philip D. (2011) (in en). A Clinical Guide for Contraception. Lippincott Williams & Wilkins. pp. 305–307. ISBN 9781608316106. Archived from the original on 2016-11-14. https://web.archive.org/web/20161114203840/https://books.google.com/books?id=f5XJtYkiJ0YC. 
  6. Contraceptive Technology. Ardent Media. Archived from the original on 2017-09-18. https://web.archive.org/web/20170918185600/https://books.google.com/books?id=txh0LpjjhkoC&pg=PA297. 
  7. The Anthem Anthology of Victorian Sonnets. Anthem Press. https://books.google.com/books?id=GQxdE8Ryz9YC&pg=PR51. 
  8. Classes and Cultures: England 1918–1951. Oxford University Press. https://books.google.com/books?id=xYuoPxzjnXUC&pg=PA305. 
  9. World Health Organization model list of essential medicines: 21st list 2019. Geneva: World Health Organization. 
  10. Contraception. John Wiley & Sons. Archived from the original on 2020-07-29. https://web.archive.org/web/20200729155934/https://books.google.com/books?id=ksjJcx1CeKcC&lpg=PA15&pg=PA15. Retrieved 2020-07-30. 
  11. AIDS and Women's Reproductive Health. Springer Science & Business Media. https://books.google.com/books?id=8KWvBQAAQBAJ&pg=PA6. 
  12. Contraceptive Use by Method: data booklet" (PDF). United Nations Department of Economic and Social Affairs. 2019. Archived (PDF) from the original on 13 December 2020. Retrieved 2 January 2021.
  13. Medical Law and Ethics. Oxford University Press. https://books.google.com/books?id=N9JFAwAAQBAJ&pg=PA271. 
  14. Current Contraceptive Use and Variation by Selected Characteristics Among Women Aged 15–44: United States, 2011–2013. 
  15. Dominance and Aggression in Humans and Other Animals: The Great Game of Life. Academic Press. https://books.google.com/books?id=6sGpDAAAQBAJ&pg=PT529.