Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B
Appearance
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B | |
---|---|
Electron micrograph of hepatitis B virus | |
Ìpínsọ́wọ̀ àti àwọn òkunfà ìta | |
ICD/CIM-10 | B16., B18.0–B18.1 B16., B18.0–B18.1 |
ICD/CIM-9 | 070.2–070.3 070.2–070.3 |
OMIM | 610424 |
DiseasesDB | 5765 |
MedlinePlus | 000279 |
Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B jẹ́ àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn hepatitis B virus (HBV) tí ó maa ń dójú kọ ẹ̀dọ̀. Ó lè fa àkóràn tí kò léwu àti èyí tí ó léwu. Ọpọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni kò mọ àwọn àmì tí a maa ń rí tí ó bá ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀. Àwọn míràn maa ń ṣe àìsàn lójijì tí ó sì maa ń mú èébì, ara òfééfèé, rírẹra, ìtọ̀ dúdú àti inú rúrú lọ́wọ́.[1] Àwọn àmì yìí maa ń lo ọ̀sẹ̀ díẹ̀, tí ìbẹ̀rẹ̀ àkóràn yìí kíì sábà fa ikú.[1][2]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "Hepatitis B Fact sheet N°204". who.int.
- ↑ Raphael Rubin; David S. Strayer (2008).