Jump to content

Cotonou Cathedral

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìta
Inú rẹ̀

Ilé ìjọsìn Notre Dame de Miséricorde, tí ọ̀pọ̀ mọ̀ sí Cotonou Cathedral, jẹ́ ilé ìjọsìn Roman Catholic kan, tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Ancien Pont Bridge no Cotonou, orílẹ̀ èdè Benin. Àwọn ènìyàn mọ́ fún ọ̀dà pupa àti funfun tí ó wà lára rẹ̀.

Ilé ìjọsìn náà jẹ́ ilé fún Roman Catholic Archdiocese of Cotonou. Wọ́n dá ẹ̀ka ìjọsìn náà kalẹ̀ ní ọjọ́ kẹríndínlógbọ̀n oṣù keje ọdún gẹ́gẹ́ bí ẹ̀ka abẹ Apostolic Vicariate of Benin Coast, orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ní ọdún 1955, wọ́n padà gbe ga sí ipò Metropolitan Archdiocese of Cotonou.