Jump to content

Orílẹ̀-èdè

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Country)
Maapu òsèlú ti àgbáyé.

Orílẹ̀-èdè ni agbègbè tàbí ilẹ̀ kàn tí ó ní ààlà, tí ó sì ní àwọn ènìyàn tí wọ́n ń ṣe àkóso lórí rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìjọba.

àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]