Dáúdà Àkànmú Epo Àkàrà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Dáúdà Àkànmú Epo-Àkàrà jẹ́ gbajú gbajà ọmó Yorùbá olórin Àwúrèbe, tí ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Ìbàdàn (23 June 1943 – August 2005).

iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olórin[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

ìlú Ìbàdàn tí ó jẹ́ ìlú tí ó tóbi jùlọ ní ilẹ̀ adúláwọ̀ ni ó ṣalátìlẹyìn fún Epo-Àkàrà, látàrí ìfẹ́ tí wọ́n ní si orin rẹ̀. Láti ilù Ìbàdàn ni òkìkìkí rẹ̀ ti tàn kálẹ̀ [[Yorùbá tókù gbogbo. Ó gbé orin jáde lábẹ́ ilé iṣẹ́ Sálíù Adétúnjí tí wọ́n mọ̀ sí "Ọmọ Ajé Records"" ní ìpínlwẹ̀ Èkó. Ẹgbéakọrin rẹ̀ ni ó kọ́kọ́ oè ní 'Dauda Àkànmú Epo-Àkàrà àti ẹẹgbé Ajísàrì', àmọ́ lẹ́yìn ìgbà tí ó ti ìlú Mẹ́kà dé ni ó yí ẹgbẹ́ orin rẹ̀ padà sí 'Alhaji Dauda Epo-Àkàrà àti ẹgbẹ́ olórin Awúrèbe [1]

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Ẹ̀kúrẹ̀rẹ́

  1. Idonije, Benson (2008-08-13). "Tribute to Awurebe King, Epo Akara". TheNigerianVoice.com. Retrieved 2019-03-14.