Dùrù Gòjé
Dùrù Gòjé jẹ́ gẹ́gẹ́ bí àwọn Awúsá ti ṣe má ń pèé, jẹ́t ohun èlò orin tí wọ̀n fi igbá ṣe, tí ó ní okùn tàbí irin méjì tó dúró gẹ́gẹ́ bí ahọ́n tí wọ́n ń fọ̀wọ́ fà kí ó lè gbé ohùn gidi jáde. Ó jẹ́ ohun èlò orin tí ó wọ́pọ̀ láàrí àwọn ẹ̀yà Awúsá. Wọ́n ma ǹ fi ọrún tí a ma ń rí lára ọfà ṣe ohun ìkọ́pá fún ohun èlò orin yìí kí ẹni tí ó ń ta gòjéó lè róun gbámú bí ó bá ń ṣeré lọ́wọ́.[1]
Lílò rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]wọ́ sábà ma ń lo gòjé láti fi gbe orin lẹ́sẹ̀ ni, tí ó sì ma ń lọ lọ́wọ́lẹ̀ bórin ṣe ń lọ ni. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ihun èlò orin mìíràn ni wọ́n lè lò pẹ̀lú gòjé bíi: pianó , ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ omele àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Àwọn orúkọ mìíràn tí ó ń jẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]àwọn orúkọ wọ̀yí ló wà ní ìbámu pẹ̀lú bí àwọn ẹ̀yà Awúsá ṣe ń pèé, yálà nínú èdè àjùmọ̀lò tàbí ẹ́ka èdè wọn. Goge (Hausa , Zarma ), gonjey (Dagomba , Gurunsi ), gonje , (Mamprusi , Dagomba), njarka (Songhay ), n'ko (Bambara , Mandinka àti èdè Mande), riti (Fula , Serer), àti nyanyeru tàbí nyanyero.
Àwọn ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
- ↑ "Full text of "Dictionary of the Hausa Language"". Internet Archive. 2016-10-23. Retrieved 2019-03-14.