Jump to content

Date plum

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán Date plum

Date-plum tí a máa ń sábà pè ní Làbídùn ní èdè Èdè Yorùbá tí wọ́n tún ń dàpè ní Diospyros lotus, tàbí Caucasian persimmon, tàbí lilac persimmon, jé ẹ̀ya ohun ọ̀gbìn tí ò wá láti inú ẹ̀yà genus Diospyros tí ó wọ́pọ̀ ní apá ilẹ̀ gúsù-mọ́-ìwọ̀-oòrùn Asia àti gúúsù mọ̀ ìla-oòrun Europe. orúkọ gẹ̀ẹ̀si rẹ̀ jẹ jáde ninu èso kékeré rẹ, èyí tí ó jẹ́ àpapọ̀ adùn èso plum àti date. ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ohun ọ̀gbìn tí a ti máá ń gbìn tipẹ́.