Jump to content

Dear Son (fíìmù 2018)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Dear Son
Fáìlì:Dear Son.png
Film poster
AdaríMohamed Ben Attia
Olùgbékalẹ̀Dora Bouchoucha Fourati
Àwọn òṣèréMohamed Dhrif
Mouna Mejri
Imen Cherif
Zakaria Ben Ayyed
OrinOmar Aloulou
Ìyàwòrán sinimáFrédéric Noirhomme
OlóòtúNadia Ben Rachid
Ilé-iṣẹ́ fíìmùLes Films du Fleuve
Tanit Films
Nomadis Images
OlùpínBac Films
Déètì àgbéjáde
  • 13 Oṣù Kàrún 2018 (2018-05-13) (Cannes)
Àkókò100 minutes
Orílẹ̀-èdèTunisia
Belgium
France
ÈdèArabic

Dear Son (Lárúbáwá: ولدي‎) jẹ́ fíìmù Tunisia tí a ṣe ní 2018 tí Mohamed Ben Attia jẹ́ olùdarí.A yàn fún ìfihàn níbi àpéjọ àwọn Olùdarí ní Àjọ fíìmù Cannes ní ọdún 2018. [1][2] Fíìmù náà ni wọ́n yàn gẹ́gẹ́ ìkópa Tunisia fún Àṣẹwá fíìmù àgbáyé tó dára jù lọ, ní ibi àmì ẹ̀yẹ akádẹ́mì kéjìléláàádọ́rin, sùgbọ́n wọn kò yàn án.[3][4]

Riadh is about to retire from his work as a forklift operator in Tunis. The life he shares with his wife Nazli revolves around their son Sami, who suffers from repeated migraine attacks while preparing for his high school exams. When he finally seems to be getting better, Sami suddenly disappears.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]