Dera Dida

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Dera Dida
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ kíkúnrẹ́rẹ́Dera Dida Yami
Ọmọorílẹ̀-èdèEthiopian
Ọjọ́ìbí26 Oṣù Kẹ̀wá 1996 (1996-10-26) (ọmọ ọdún 27)
Sport
Erẹ́ìdárayáSport of athletics
Event(s)Long-distance running

Dera Dida Yami ni a bini ọjọ kẹrin dinlọgbọn, óṣu october, ọdun 1996 jẹ elere sisa lobinrin ti ilẹ Ethiopia to da lori ọna jinjin[1][2].

Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ni ọdun 2017, Dera kopa ninu idije agbaye lori ere sisa ti mita ti ẹgbẹrun mẹwa pẹlu wakati 31:51:75[3]. Ni ọdun 2019,Dera gba ami ẹyẹ ti ọla ti silver ninu Idije Agbaye ti IAAF to waye ni Aarhus, Denmark. Ni ọdun 2019, Dera ami ẹyẹ ti ọla ti idẹ ninu ayẹyẹ ti mita ẹgbẹrun mẹwa[4].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Dera Biography
  2. Dera Dida Profile
  3. Senior Women's Race 10k
  4. IAAF